1 Kíróníkà 28:11 BMY

11 Nígbà náà, Dáfídì fún Sólómónì ọmọ Rẹ̀ ní ètò fún èbúté ilé Olúwa náà, kíkọ́ ọ Rẹ̀, àwọn yàrá ìṣúra Rẹ̀, ibi òkè Rẹ̀, àwọn ìyẹ̀wù Rẹ̀ àti ibi ìpètù sí Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:11 ni o tọ