1 Kíróníkà 28:17 BMY

17 Ìwọ̀n kìkìdá wúrà fún àwọn àmúga ìjẹun, àwọn ìbùwọ̀n ọpọ́n àti àwọn ìkòkò ìpọnmi; Ìwọ̀n wúrà fún gbogbo àwo pọ̀ọ́kọ̀; fàdákà;

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:17 ni o tọ