1 Kíróníkà 28:20 BMY

20 Dáfídì tún sọ fún Sólómónì ọmọ Rẹ̀ pé, “Jẹ́ alágbára kí o sì gbóyà, kí o sì ṣe isẹ́ náà. Má ṣe bẹ̀rù tàbí dààmú, nítorí Olúwa Ọlọ́run, Ọlọ́run mi, wà pẹ̀lú rẹ. Òun kì yóò sì jọ ọ kule tàbí kọ Ọ sílẹ̀ títí gbogbo iṣẹ́ fún ìsìn ní ti ilé Olúwa yóò fi parí.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:20 ni o tọ