1 Kíróníkà 28:3 BMY

3 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run sọ fún mi pé: Ìwọ kò gbodò kọ́ ilé fún orúkọ mi, nítorí ìwọ jẹ́ jagunjagun, ìwọ sì ti tàjẹ̀sílẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:3 ni o tọ