1 Kíróníkà 29:1 BMY

1 Nígbà náà, ọba Dáfídì sọ fún gbogbo àpéjọ pé: “Ọmọ mi Sólomónì, èyí tí Ọlọ́run ti yàn, ṣì kéré ó sì jẹ́ aláìmòye. Iṣẹ́ náà tóbi, nítorí ìkọ́lé bí ti ààfin kì í ṣe fún ènìyàn ṣùgbọ́n fún Olúwa Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:1 ni o tọ