1 Kíróníkà 29:23 BMY

23 Bẹ́ẹ̀ ni Sólómónì jókòó lórí ìtẹ́ Olúwa gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò bàbá a Rẹ̀ Dáfídì. O ṣe àṣeyọrí, gbogbo Ísírẹ́lì sì gbọ́ràn sí i lẹ́nu.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:23 ni o tọ