1 Kíróníkà 29:29 BMY

29 Ní ti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà ìjọba ọba Dáfídì, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, a kọ wọ́n sínú ìwe ìrántí ti Sámúẹ́lì aríran, ìwé ìrántí ti Nátanì wòlíì àti ìwé ìrántí ti Gádì aríran,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:29 ni o tọ