1 Kíróníkà 29:3 BMY

3 Yàtọ̀ fún èyí, nínú ìfọkànsìn mi sí ilé Ọlọ́run mi, èmí fi ìṣúra mi tìkalára mí ti wúrà àti fàdákà fún ilé Ọlọ́run mi, jù gbogbo Rẹ̀ lọ, èmi ti pèṣè fún ilé mímọ́ ti Olúwa yìí:

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:3 ni o tọ