1 Kíróníkà 3:1 BMY

1 Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dáfídì tí a bí fún un ní Hébírónì:Àkọ́bí sì ni Ámínónì ọmọ Áhínóámù ti Jésírẹ́lì;èkejì sì ni Dáníẹ́lì ọmọ Ábígáílì ará Kárímélì;

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3

Wo 1 Kíróníkà 3:1 ni o tọ