1 Kíróníkà 4:19 BMY

19 Àwọn ọmọ aya Hódíyà arábìnrin Náhámù:Baba Kéílà ará Gárímì, àti Ésítémóà àwọn ará Mákà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:19 ni o tọ