1 Kíróníkà 4:21 BMY

21 Àwọn ọmọ Ṣélà ọmọ Júdà:Érì baba Lékà, Ládà baba Máréṣà àti àwọn ìdílé ilé àwọn tí ń wun aṣọ oníṣẹ́ ní Bẹti-Áṣíbéà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:21 ni o tọ