1 Kíróníkà 4:33 BMY

33 Àti gbogbo ìletò tí ó wà ní agbégbé àti gẹ́gẹ́ bí ó ti dé Bálì Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn, wọ́n sì pa ìwé ìtàn ìdílé mọ́.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:33 ni o tọ