1 Kíróníkà 5:10 BMY

10 Àti ní ọjọ́ Ṣọ́ọ̀lù, wọ́n bá àwọn ọmọ Hágárì jagun, ẹni tí ó ṣubú nípa ọwọ́ wọn; wọ́n sì ń gbé inú àgọ́ wọn ní gbogbo ilẹ̀ àríwá Gílíádì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 5

Wo 1 Kíróníkà 5:10 ni o tọ