1 Kíróníkà 5:22 BMY

22 Nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ṣubú tí a pa, nítorí láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ogun náà, wọ́n sì jókòó ní ipò wọn títí di ìgbà ìkólọ sí ìgbékùn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 5

Wo 1 Kíróníkà 5:22 ni o tọ