1 Kíróníkà 5:24 BMY

24 Wọ̀nyí sì ni àwọn olórí ilé àwọn baba wọn. Éférì, Ísì, Élíélì, Ásíríélì, Jérémáíà, Hódáfíà àti Jáhídíélì àwọn alágbára akọni ọkùnrin, ọkùnrin olókìkí, àti olórí ilé àwọn baba wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 5

Wo 1 Kíróníkà 5:24 ni o tọ