11 Áṣáríyà baba ÁmáríyàÁmáríyà baba Áhítúbì
12 Áhítúbì baba Ṣádókù.Ṣádókù baba Ṣálúmù,
13 Ṣálúmù baba Hílíkíyà,Hílíkíyà baba Áṣáríyà,
14 Áṣáríyà baba Ṣéráíà,pẹ̀lú Ṣéráíà baba Jéhósádákì
15 A kó Jéhósádákì lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Júdà àti Jérúsálẹ́mù kúrò ní ìlú nípaṣẹ̀ Nebukadinésárì.
16 Àwọn ọmọ Léfì:Gérísónì, kóhátì àti Mérárì.
17 Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Géríṣónì:Líbínì àti Ṣíméhì.