14 Áṣáríyà baba Ṣéráíà,pẹ̀lú Ṣéráíà baba Jéhósádákì
15 A kó Jéhósádákì lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Júdà àti Jérúsálẹ́mù kúrò ní ìlú nípaṣẹ̀ Nebukadinésárì.
16 Àwọn ọmọ Léfì:Gérísónì, kóhátì àti Mérárì.
17 Wọ̀nyí ni àwọn orúkọ àwọn ọmọ Géríṣónì:Líbínì àti Ṣíméhì.
18 Àwọn ọmọ Kéhátì:Ámírámù, Íṣárì, Hébírónì àti Húsíélì.
19 Àwọn ọmọ Mérárì:Máhílì àti Múṣì.Wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ará Léfì tí a kọ ní ṣíṣẹ̀ ń tẹ̀lé gẹ́gẹ́ bí baba wọn:
20 Ti Gérísómù:Líbínì ọmọkùnrin Rẹ̀, JéhátìỌmọkùnrin Rẹ̀, Ṣímà ọmọkùnrin Rẹ̀,