25 Àwọn ìran ọmọ Élíkánáhì:Ámásáyì, Áhímótì
26 Élíkáná ọmọ Rẹ̀, Ṣófáì ọmọ Rẹ̀Náhátì ọmọ Rẹ̀,
27 Élíábù ọmọ Rẹ̀,Jéríhámù ọmọ Rẹ̀, Élíkáná ọmọ Rẹ̀àti Ṣámúẹ́lì ọmọ Rẹ̀.
28 Àwọn ọmọ Ṣámúẹ́lì:Jóẹ́lì àkọ́bíàti Ábíjà ọmọẹlẹ́ẹ̀kejì.
29 Àwọn ìran ọmọ Mérárì:Máhílì, Líbínì ọmọ Rẹ̀.Ṣíméhì ọmọ Rẹ̀, Úṣáhì ọmọ Rẹ̀.
30 Ṣíméà, ọmọ Rẹ̀ Hágíáhì ọmọ Rẹ̀àti Ásáíáhì ọmọ Rẹ̀.
31 Èyí ní àwọn ọkùnrin Dáfídì tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sínmìn níbẹ̀.