1 Kíróníkà 6:32 BMY

32 Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin ńiwájú Àgọ́ ìpàdé títí tí Ṣólómónì fi kọ́ ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù. Wọ́n se iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6

Wo 1 Kíróníkà 6:32 ni o tọ