38 ọmọ Íṣíhárì, ọmọ Kóhátìọmọ Léfì, ọmọ Ísírẹ́lì;
39 Hémánì sì darapọ̀ mọ́ Ásátì, ẹni tí Ó sìn ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀:Ásátì ọmọ bérékíáhì, ọmọ Ṣíméà,
40 Ọmọ Míkáélì, ọmọ Bááséíáhì,ọmọ Málíkíjáhì
41 Ọmọ Étínì,ọmọ Ṣéráhì, ọmọ Ádáyà,
42 Ọmọ Étanì, ọmọ Ṣímáhì,ọmọ Ṣíméhì,
43 Ọmọ Jáhátì,ọmọ Gérísíónì, ọmọ Léfì;
44 láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Mérárì wà ní ọwọ́ òsì Rẹ̀:Étanì ọmọ Kísì, ọmọ Ábídì,ọmọ Málúkì,