41 Ọmọ Étínì,ọmọ Ṣéráhì, ọmọ Ádáyà,
42 Ọmọ Étanì, ọmọ Ṣímáhì,ọmọ Ṣíméhì,
43 Ọmọ Jáhátì,ọmọ Gérísíónì, ọmọ Léfì;
44 láti ìbákẹ́gbẹ́ wọn, àwọn ará Mérárì wà ní ọwọ́ òsì Rẹ̀:Étanì ọmọ Kísì, ọmọ Ábídì,ọmọ Málúkì,
45 Ọmọ Háṣábíáhìọmọ Ámásáyà, ọmọ Hítíkíáhì,
46 Ọmọ Ámíṣì ọmọ Bánì,ọmọ Ṣémérì,
47 Ọmọ Máhílì,ọmọ Múṣì, ọmọ Mérárì,ọmọ Léfì.