1 Kíróníkà 6:62 BMY

62 Àwọn ìran ọmọ Géríṣómù, sí ìdílé ni a pín ìlú mẹ́talá fún láti ẹ̀yà àwọn ẹ̀yà Íṣákárì, Áṣérì àti Náfítalì, àti láti apá ẹ̀yà Mánásè tí ó wà ní Básánì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6

Wo 1 Kíróníkà 6:62 ni o tọ