1 Kíróníkà 6:76 BMY

76 Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Náfítalìwọ́n gba Kédésì ní Gálílì, Hámoníà Kíríátaímù, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6

Wo 1 Kíróníkà 6:76 ni o tọ