78 Láti ẹ̀yà Rúbẹ́nì rékọjá Jódánì ìlà oòrùn Jẹ́ríkòwọ́n gba Bésérì nínú ihà Jáhíṣáhì,
79 Kédémótì àti Méfátù, lápapọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko, tútù wọn;
80 Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Gádìwọ́n gba Rámóà ní Gílíádì Máhánáímù,
81 Hésíbónì àti Jáṣérì lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ilẹ̀ pápá oko tútù wọn.