9 Áhímásì baba Áṣáríyà,Ásáríyà baba Jóhánánì,
10 Jóhánánì baba Áṣáríyà (Òhun ni ó sìn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà nínú ilé Olúwa tí Sólómónì kọ́ sí Jérúsálẹ́mù),
11 Áṣáríyà baba ÁmáríyàÁmáríyà baba Áhítúbì
12 Áhítúbì baba Ṣádókù.Ṣádókù baba Ṣálúmù,
13 Ṣálúmù baba Hílíkíyà,Hílíkíyà baba Áṣáríyà,
14 Áṣáríyà baba Ṣéráíà,pẹ̀lú Ṣéráíà baba Jéhósádákì
15 A kó Jéhósádákì lẹ́rú nígbà tí Olúwa lé Júdà àti Jérúsálẹ́mù kúrò ní ìlú nípaṣẹ̀ Nebukadinésárì.