1 Kíróníkà 7:15 BMY

15 Mákírì sì mú ìyàwó láti àárin àwọn ará Hípímù àti Ṣúpímù. Orúkọ arábìnrin Rẹ̀ a má a jẹ́ Máákà.Orúkọ ìran ọmọ mìíràn a má a jẹ́ Ṣélóféhádì, tí ó ní àwọn ọmọbìnrin nìkan ṣoṣo.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 7

Wo 1 Kíróníkà 7:15 ni o tọ