1 Kíróníkà 7:23 BMY

23 Nígbà náà, ó sùn pẹ̀lú, ìyàwó Rẹ̀, ó sì lóyún ó sì bí ọmọkùnrin kan. Ó sì sọ ọ́ ní Béríà nítorí òfò ti wà nínú ìdílé náà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 7

Wo 1 Kíróníkà 7:23 ni o tọ