3 Àwọn ọmọ, Húṣì:Ísíráhíà.Àwọn ọmọ Ísíráhíà:Míkáélì Ọbádáyà, Jóẹ́lì àti Ísíhíáhì. Gbogbo àwọn máràrùn sì jẹ́ olóyè.
Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 7
Wo 1 Kíróníkà 7:3 ni o tọ