36 Àwọn ọmọ Ṣófáhì:Ṣúà, Háníférì, Ṣúálì, Bérì Ímírà.
37 Béṣérì Hódì, Ṣámà, Ṣílísà, Ítíránì àti Bérà.
38 Àwọn ọmọ Jétérì:Jéfúnè Písífà àti Árà.
39 Àwọn ọmọ Úlà:Árà Háníélì àti Résíà.
40 Gbogbo wọ̀nyí jẹ́ ìran ọmọ Áṣérì olórí ìdílé, àwọn okùnrin tí a yàn àwọn ògbóyà jagunjagun àti àwọn adarí tí ó dúró sinsin. Iye àwọn ọkùnrin tí ó setan fún ogun, gẹ́gẹ́ bí à ti se kọ ọ́ lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé wọn láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n.