1 Bẹ́ńjámínì jẹ́ bàbá Bélà àkọ́bí Rẹ̀,Áṣíbélì ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Áhárá ẹ̀ẹ̀kẹ́ta,
2 Nóhà ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Ráfà ẹ̀ẹ̀karùnún.
3 Àwọn ọmọ Bélà jẹ́:Ádárì, Gérà, Ábíhúdì,
4 Ábísúà, Námánì, Áhóà,