23 Ábídónì, Ṣíkírì, Hánánì,
24 Hánáníyà, Élámù, Ánítótíjáhì,
25 Ífédíà Pénúélì jẹ́ àwọn ọmọ Ṣásákì.
26 Ṣámíséráì, Ṣéháríà, Átalíà
27 Járéṣíà Élíjà àti Ṣíkírì jẹ́ àwọn ọmọ Jéróhámù.
28 Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ó lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù.
29 Jélíélì, baba a Gíbíónì ń gbé ní Gíbíónì.Ìyáwó o Rẹ̀ a má jẹ́ Mákà,