1 Kíróníkà 9:13 BMY

13 Àwọn àlùfáà, tí wọ́n jẹ́ àwọn olórí àwọn ìdílé, tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀sán ó dín méjì (1,760). Wọ́n jẹ́ alágbára ọkùnrin, tí wọ́n lè dúró fún iṣẹ́ ìránṣẹ́ nínú ilé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:13 ni o tọ