1 Kíróníkà 9:26 BMY

26 Ṣùgbọ́n àwọn olórí olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí wọ́n jẹ́ ará Léfì ni a yàn fún àwọn iyàrá àti àwọn àpótí ìsúra ní ilé Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:26 ni o tọ