1 Kíróníkà 9:31 BMY

31 Ará Léfì tí a sọ ní Mátítíhíà, àkọ́bí ọmọkùnrin Ṣálúmì ará kórà ni a yàn sí ìdí dídín àkàrà ọrẹ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:31 ni o tọ