1 Kíróníkà 9:33 BMY

33 Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọkùnrin, olórí àwọn ìdílé Léfì dúró nínú àgọ́ ilé Olúwa, wọn kò sì se lára isẹ́ ìsìn yòókù nítorí wọ́n ń se isẹ́ náà lọ́sán, lóru.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:33 ni o tọ