2 Kíróníkà 1:4 BMY

4 Nísinsinyìí, Dáfídì ti gbé àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run wá láti Kiriati-Jéárímù sí ibi tí ó ti pèsè fún un, nítorí ó ti kọ́ àgọ́ fún un ni Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:4 ni o tọ