2 Kíróníkà 1:5 BMY

5 Ṣùgbọ́n pẹpẹ idẹ tí Bésálélì ọmọ Úrì, ọmọ Húrù, ti ṣe wà ní Gíbíónì níwájú àgọ́ Olúwa: Bẹ́ẹ̀ ni Sólómónì àti gbogbo àpèjọ béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ níbẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:5 ni o tọ