2 Kíróníkà 13:7 BMY

7 Àwọn ènìyàn lásán aláìwúlò péjọ yí i ká, wọ́n sì kẹ̀yìn sí Réhóbóámù ọmọ Sólomónì ní ìgbà tí ó sì kéré tí kò lè pinnu fún ra rẹ̀, tí kò lágbára tó láti takò wọ́n.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 13

Wo 2 Kíróníkà 13:7 ni o tọ