2 Kíróníkà 14:15 BMY

15 Wọ́n kọ lu àwọn ibùdó àwọn darandaran, wọ́n sì gbé àwọn ọ̀wọ́-ẹran àgùntàn àti àwọn ewúrẹ́ àti àwọn ìbákasẹ. Nígbà náà wọ́n padà sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:15 ni o tọ