2 Kíróníkà 14:3 BMY

3 Ó gbé àwọn pẹpẹ àjèjì kúrò àti àwọn ibi gíga. Ó fọ́ àwọn òkúta tí a yà sọ́tọ̀, ó sì gé àwọn òpó Áṣérà bolẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 14

Wo 2 Kíróníkà 14:3 ni o tọ