2 Kíróníkà 18:10 BMY

10 Nísinsin yìí Sedekáyà ọmọ Kénánà sì ti ṣe ìwo irin, ó sì wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa sọ: pẹ̀lú èyí ìwọ yóò kan àwọn ará Síríà títí ìwọ ó fi pa wọ́n run.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:10 ni o tọ