2 Kíróníkà 18:9 BMY

9 Wọ́n wọ aṣọ Ìgúnwà wọn, ọba Ísírẹ́lì àti Jehóṣáfátì ọba Júdà wọ́n jókòó sórí ìtẹ́ wọ́n ní ìta ẹnu bodè Samaríà, pẹ̀lú gbogbo àwọn wòlíì tí ń sọtẹ́lẹ̀ níwájú wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:9 ni o tọ