2 Kíróníkà 18:20 BMY

20 Ní ìparí, ni ẹ̀mí kan wá ṣíwájú, ó dúró níwájú Olúwa ó sì wí pé, ‘Èmi yóò tàn án.’“ ‘Nípa ọ̀nà wo?’ Olúwa beèrè.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:20 ni o tọ