2 Kíróníkà 18:19 BMY

19 Olúwa sì wí pé, ‘Ta ni yóò tan Áhábù ọba Ísírẹ́lì lọ sí Rámátì Giléádì kí ó sì lọ kú ikú rẹ̀ níbẹ̀?’“Èkínní sì sọ tìhín, òmíràn sì sọ tọ̀hún.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:19 ni o tọ