2 Kíróníkà 18:22 BMY

22 “Bẹ́ẹ̀ ni nísinsìn yìí Olúwa ti fi ẹ̀mí èké sí ẹnu àwọn wòlíì rẹ. Olúwa sì ti sọ ibi sí ọ.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:22 ni o tọ