2 Kíróníkà 18:29 BMY

29 Ọba Ísírẹ́lì sọ fún Jéhóṣáfátì pé, “Èmi yóò lọ sí ojú ìjà, ṣùgbọ́n ìwọ wọ aṣọ ìgunwà rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì pa aṣọ rẹ̀ dà, ó sì lọ sí ojú ìjà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:29 ni o tọ