2 Kíróníkà 18:30 BMY

30 Nísinsìn yìí ọba Síríà ti pàsẹ fún àwọn olórí kẹ̀kẹ́ tí ó wà ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé, “Ẹ má ṣe jà pẹ̀lú ẹnìkankan, èwe tàbí àgbà àyàfi ọba Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 18

Wo 2 Kíróníkà 18:30 ni o tọ