2 Kíróníkà 2:17 BMY

17 Sólómónì ka iye àwọn àjèjì tí ó wà ní Ísírẹ́lì lẹ́yìn kíka iye wọn tí baba a rẹ̀ Dáfídì ti ṣe; a sì ka iye wọn sí (153,600) ọ̀kẹ́mẹ́jọ ó dín egbéjì-lélọ́gbọ̀n.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:17 ni o tọ