2 Kíróníkà 2:18 BMY

18 Ó sì yan ẹgbàá márùndínlógójì nínú wọn láti ru ẹrù, àti ọ̀kẹ́ mẹ́rin láti ṣe àgọ́ òkúta lórí òkè, àti egbéjìdínlógún alábojútó láti kó àwọn ènìyàn ṣíṣẹ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 2

Wo 2 Kíróníkà 2:18 ni o tọ