2 Kíróníkà 3:1 BMY

1 Nígbà náà, Sólómónì bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ́ ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù lórí òkè Móríà, níbi tí Olúwa ti farahan bàbá a rẹ̀ Dáfídì. Ní ori ilẹ̀ ìpakà Áráúnà ará Jébúsì, ibi tí Dáfídì pèsè.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:1 ni o tọ